Jẹ́nẹ́sísì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí àwọn omi tó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́ jọ síbì kan, kí ilẹ̀ sì fara hàn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
9 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí àwọn omi tó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́ jọ síbì kan, kí ilẹ̀ sì fara hàn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.