ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 38:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ta ló sì fi àwọn ilẹ̀kùn sé òkun,+

      Nígbà tó tú jáde látinú ikùn,*

  • Jóòbù 38:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Mo sì sọ pé, ‘Ibi tí o lè dé nìyí, má kọjá ibẹ̀;

      Ìgbì rẹ tó ń ru sókè kò ní kọjá ibí yìí’?+

  • Sáàmù 104:6-9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 O fi ibú omi bò ó bí aṣọ.+

      Omi náà bo àwọn òkè.

       7 Bí wọ́n ṣe gbọ́ ìbáwí rẹ, wọ́n fẹsẹ̀ fẹ;+

      Bí wọ́n ṣe gbọ́ ìró ààrá rẹ, ìbẹ̀rù mú kí wọ́n sá lọ

       8 —Àwọn òkè lọ sókè,+ àwọn àfonífojì sì lọ sílẹ̀—

      Sí ibi tí o ṣe fún wọn.

       9 O pa ààlà tí wọn ò gbọ́dọ̀ kọjá,+

      Kí wọ́n má bàa bo ayé mọ́.

  • Sáàmù 136:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ó tẹ́ ayé sórí omi,+

      Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́