Jóòbù 39:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “Ṣé o mọ ìgbà tí àwọn ewúrẹ́ orí òkè máa ń bímọ?+ Ṣé o ti rí àgbọ̀nrín tó ń bímọ rí?+