Jẹ́nẹ́sísì 1:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run rí gbogbo ohun tó ti ṣe, sì wò ó! ó dára gan-an.+ Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kẹfà.
31 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run rí gbogbo ohun tó ti ṣe, sì wò ó! ó dára gan-an.+ Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kẹfà.