Diutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+ Sáàmù 104:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn iṣẹ́ rẹ mà pọ̀ o, Jèhófà!+ Gbogbo wọn lo fi ọgbọ́n ṣe.+ Ayé kún fún àwọn ohun tí o ṣe. 1 Tímótì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí gbogbo ohun tí Ọlọ́run dá ló dára,+ kò sì yẹ ká kọ ohunkóhun+ tí a bá fi ìdúpẹ́ gbà á,
4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+