Sáàmù 77:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Màá ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ,Màá sì ronú jinlẹ̀ nípa àwọn ohun tí o ṣe.+ Sáàmù 119:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jẹ́ kí n mọ ìtumọ̀* àwọn àṣẹ rẹ,Kí n lè máa ronú lórí* àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ.+