Sáàmù 31:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ìyìn ni fún Jèhófà,Nítorí ó ti fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi lọ́nà àgbàyanu+ ní ìlú tí ọ̀tá dó tì.+ Ìdárò 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ ni ò jẹ́ ká ṣègbé,+Nítorí àánú rẹ̀ kò ní dópin láé.+
21 Ìyìn ni fún Jèhófà,Nítorí ó ti fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi lọ́nà àgbàyanu+ ní ìlú tí ọ̀tá dó tì.+