Sáàmù 78:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó la àpáta ní aginjù,Ó jẹ́ kí wọ́n mu àmutẹ́rùn bíi pé látinú ibú omi.+ 16 Ó mú kí omi ṣàn jáde látinú àpáta,Ó sì mú kí omi ṣàn wálẹ̀ bí odò.+
15 Ó la àpáta ní aginjù,Ó jẹ́ kí wọ́n mu àmutẹ́rùn bíi pé látinú ibú omi.+ 16 Ó mú kí omi ṣàn jáde látinú àpáta,Ó sì mú kí omi ṣàn wálẹ̀ bí odò.+