ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 11:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Jóṣúà wá gba gbogbo ilẹ̀ náà, bí Jèhófà ṣe ṣèlérí fún Mósè,+ Jóṣúà sì fi ṣe ogún fún Ísírẹ́lì, bí ìpín wọn, pé kí wọ́n pín in láàárín àwọn ẹ̀yà wọn.+ Ogun sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ náà.+

  • Jóṣúà 21:43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Jèhófà fún Ísírẹ́lì ní gbogbo ilẹ̀ tó búra pé òun máa fún àwọn baba ńlá wọn,+ wọ́n gbà á, wọ́n sì ń gbé inú rẹ̀.+

  • Nehemáyà 9:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 “O fún wọn ní àwọn ìjọba àti àwọn èèyàn, o sì pín wọn ní ẹyọ-ẹyọ fún wọn,+ kí wọ́n lè gba ilẹ̀ Síhónì,+ ìyẹn ilẹ̀ ọba Hẹ́ṣíbónì+ àti ilẹ̀ Ógù+ ọba Báṣánì.

  • Sáàmù 78:55
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 55 Ó lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde níwájú wọn;+

      Ó fi okùn ìdíwọ̀n pín ogún fún wọn;+

      Ó mú kí àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì máa gbé inú ilé wọn.+

  • Ìṣe 13:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Lẹ́yìn tó pa orílẹ̀-èdè méje run ní ilẹ̀ Kénáánì, ó fi ilẹ̀ wọn ṣe ogún fún àwọn baba ńlá wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́