Sáàmù 143:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, jọ̀wọ́ jẹ́ kí n máa wà láàyè nítorí orúkọ rẹ. Gbà mí* nínú wàhálà nítorí òdodo rẹ.+ Ìsíkíẹ́lì 20:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́, mo gbé ìgbésẹ̀ torí orúkọ mi, kí wọ́n má bàa kó ẹ̀gàn bá a lójú àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n rí i nígbà tí mo mú wọn* jáde.+
14 Àmọ́, mo gbé ìgbésẹ̀ torí orúkọ mi, kí wọ́n má bàa kó ẹ̀gàn bá a lójú àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n rí i nígbà tí mo mú wọn* jáde.+