Sáàmù 31:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jèhófà, ìwọ ni mo fi ṣe ibi ààbò mi.+ Kí ojú má tì mí láé.+ Gbà mí sílẹ̀ nítorí òdodo rẹ.+