Sáàmù 22:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìwọ ni àwọn baba wa gbẹ́kẹ̀ lé;+Wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé ọ, o sì ń gbà wọ́n sílẹ̀.+ 5 Ìwọ ni wọ́n ké pè, o sì gbà wọ́n;Wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé ọ, o ò sì já wọn kulẹ̀.*+ Róòmù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìwé Mímọ́ sọ pé: “Kò sí ẹni tó bá gbé ìgbàgbọ́ rẹ̀ lé e tó máa rí ìjákulẹ̀.”+
4 Ìwọ ni àwọn baba wa gbẹ́kẹ̀ lé;+Wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé ọ, o sì ń gbà wọ́n sílẹ̀.+ 5 Ìwọ ni wọ́n ké pè, o sì gbà wọ́n;Wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé ọ, o ò sì já wọn kulẹ̀.*+