Àìsáyà 49:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Màá mú kí àwọn tó ń fìyà jẹ ọ́ jẹ ẹran ara tiwọn,Wọ́n sì máa mu ẹ̀jẹ̀ ara wọn yó bí ẹni mu wáìnì tó dùn. Gbogbo èèyàn* sì máa mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,+Olùgbàlà rẹ+ àti Olùtúnrà rẹ,+Alágbára Jékọ́bù.”+
26 Màá mú kí àwọn tó ń fìyà jẹ ọ́ jẹ ẹran ara tiwọn,Wọ́n sì máa mu ẹ̀jẹ̀ ara wọn yó bí ẹni mu wáìnì tó dùn. Gbogbo èèyàn* sì máa mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,+Olùgbàlà rẹ+ àti Olùtúnrà rẹ,+Alágbára Jékọ́bù.”+