Àìsáyà 60:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 O sì máa mu wàrà àwọn orílẹ̀-èdè,+O máa mu ọmú àwọn ọba;+Wàá sì mọ̀ dájú pé èmi Jèhófà ni Olùgbàlà rẹ,Alágbára Jékọ́bù sì ni Olùtúnrà rẹ.+
16 O sì máa mu wàrà àwọn orílẹ̀-èdè,+O máa mu ọmú àwọn ọba;+Wàá sì mọ̀ dájú pé èmi Jèhófà ni Olùgbàlà rẹ,Alágbára Jékọ́bù sì ni Olùtúnrà rẹ.+