Nọ́ńbà 16:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Iná sì wá látọ̀dọ̀ Jèhófà,+ ó jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin tó ń sun tùràrí+ run.