-
Nọ́ńbà 16:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Kí kálukú mú ìkóná rẹ̀, kó fi tùràrí sí i, kí ẹnì kọ̀ọ̀kan mú ìkóná rẹ̀ wá síwájú Jèhófà, kó jẹ́ igba ó lé àádọ́ta (250) ìkóná. Kí ìwọ àti Áárónì náà wà níbẹ̀, kí kálukú mú ìkóná rẹ̀ dání.”
-
-
Sáàmù 106:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Iná sọ láàárín àwùjọ wọn;
Ọwọ́ iná jó àwọn ẹni burúkú run.+
-