-
Jóṣúà 17:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àmọ́ àwọn àtọmọdọ́mọ Mánásè ò lè gba àwọn ìlú yìí; àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé ilẹ̀ yìí.+
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 1:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àmọ́ àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì ò lé àwọn ará Jébúsì tó ń gbé Jerúsálẹ́mù kúrò, torí náà, àwọn ará Jébúsì ṣì ń bá àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì gbé ní Jerúsálẹ́mù títí dòní.+
-