Sáàmù 79:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọ́run ìgbàlà wa,+Nítorí orúkọ rẹ ológo;Gbà wá sílẹ̀, kí o sì dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá* nítorí orúkọ rẹ.+
9 Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọ́run ìgbàlà wa,+Nítorí orúkọ rẹ ológo;Gbà wá sílẹ̀, kí o sì dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá* nítorí orúkọ rẹ.+