-
1 Àwọn Ọba 17:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àmọ́ lẹ́yìn ọjọ́ mélòó kan, odò náà gbẹ+ torí pé òjò ò rọ̀ ní ilẹ̀ náà.
-
-
Àìsáyà 42:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Màá sọ àwọn òkè ńlá àti àwọn òkè kéékèèké di ahoro,
Màá sì mú kí gbogbo ewéko wọn gbẹ dà nù.
-
-
Émọ́sì 4:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 ‘Mo tún fawọ́ òjò sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ yín nígbà tí ìkórè ṣì ku oṣù mẹ́ta;+
Mo mú kí òjò rọ̀ sí ìlú kan àmọ́ mi ò jẹ́ kó rọ̀ sí ìlú míì.
Òjò máa rọ̀ sí ilẹ̀ kan,
Àmọ́ ilẹ̀ tí òjò kò rọ̀ sí máa gbẹ.
-