ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+

  • Diutarónómì 28:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ojú ọ̀run tó wà lókè orí rẹ máa di bàbà, ilẹ̀ tó sì wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ máa di irin.+

  • Jeremáyà 14:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ǹjẹ́ ìkankan lára àwọn òrìṣà lásánlàsàn tí àwọn orílẹ̀-èdè ń bọ lè rọ òjò,

      Àbí ṣé ọ̀run fúnra rẹ̀ pàápàá lè dá rọ ọ̀wààrà òjò?

      Ìwọ nìkan lo lè ṣe é, Jèhófà Ọlọ́run wa.+

      A sì ní ìrètí nínú rẹ,

      Nítorí ìwọ nìkan ló ń ṣe gbogbo nǹkan yìí.

  • Lúùkù 4:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Bí àpẹẹrẹ, mò ń sọ fún yín ní tòótọ́ pé: Ọ̀pọ̀lọpọ̀ opó ló wà ní Ísírẹ́lì nígbà ayé Èlíjà, nígbà tí a sé ọ̀run pa fún ọdún mẹ́ta àti oṣù mẹ́fà, tí ìyàn sì mú gidigidi ní gbogbo ilẹ̀ náà.+

  • Jémíìsì 5:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ẹni tó máa ń mọ nǹkan lára bíi tiwa ni Èlíjà, síbẹ̀, nígbà tó gbàdúrà taratara pé kí òjò má rọ̀, òjò ò rọ̀ sórí ilẹ̀ náà fún ọdún mẹ́ta àti oṣù mẹ́fà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́