12 Jèhófà máa ṣí ọ̀run, ilé ìkẹ́rùsí rẹ̀ tó dáa fún ọ, láti rọ òjò sórí ilẹ̀ rẹ ní àkókò+ rẹ̀, kó sì bù kún gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. O máa yá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè ní nǹkan, àmọ́ kò ní sóhun tó máa mú kí o yá+ nǹkan.
23 Ó máa rọ òjò sí ohun tí o gbìn sínú ilẹ̀,+ oúnjẹ tí ilẹ̀ bá sì mú jáde máa pọ̀ rẹpẹtẹ, ó sì máa lọ́ràá.*+ Ní ọjọ́ yẹn, ẹran ọ̀sìn rẹ máa jẹko ní àwọn pápá tó fẹ̀.+