Sáàmù 146:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹni tó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn tí wọ́n lù ní jìbìtì,Ẹni tó ń fún àwọn tí ebi ń pa lóúnjẹ.+ Jèhófà ń dá àwọn ẹlẹ́wọ̀n* sílẹ̀.+ Lúùkù 1:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 ó ti fi àwọn ohun rere tẹ́ àwọn tí ebi ń pa lọ́rùn dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,+ ó sì ti mú kí àwọn tó lọ́rọ̀ lọ lọ́wọ́ òfo.
7 Ẹni tó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn tí wọ́n lù ní jìbìtì,Ẹni tó ń fún àwọn tí ebi ń pa lóúnjẹ.+ Jèhófà ń dá àwọn ẹlẹ́wọ̀n* sílẹ̀.+
53 ó ti fi àwọn ohun rere tẹ́ àwọn tí ebi ń pa lọ́rùn dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,+ ó sì ti mú kí àwọn tó lọ́rọ̀ lọ lọ́wọ́ òfo.