-
Sáàmù 107:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ó mú wọn jáde nínú òkùnkùn biribiri,
Ó sì fa ìdè wọn já.+
-
-
Sáàmù 142:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Mú mi* jáde kúrò nínú àjà ilẹ̀
Kí n lè máa yin orúkọ rẹ.
Kí àwọn olódodo yí mi ká,
Nítorí o ti ṣemí lóore.
-