Diutarónómì 33:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Iyì rẹ̀ dà bíi ti àkọ́bí akọ màlúù,Ìwo akọ màlúù igbó sì ni àwọn ìwo rẹ̀. Ó máa fi ti* àwọn èèyàn,Gbogbo wọn pa pọ̀ títí dé àwọn ìkángun ayé. Ẹgbẹẹgbàárùn-ún Éfúrémù + ni wọ́n,Ẹgbẹẹgbẹ̀rún Mánásè sì ni wọ́n.”
17 Iyì rẹ̀ dà bíi ti àkọ́bí akọ màlúù,Ìwo akọ màlúù igbó sì ni àwọn ìwo rẹ̀. Ó máa fi ti* àwọn èèyàn,Gbogbo wọn pa pọ̀ títí dé àwọn ìkángun ayé. Ẹgbẹẹgbàárùn-ún Éfúrémù + ni wọ́n,Ẹgbẹẹgbẹ̀rún Mánásè sì ni wọ́n.”