Sáàmù 37:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nítorí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo,Kò sì ní kọ àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀ sílẹ̀.+ ע [Áyìn] Ìgbà gbogbo ni yóò máa ṣọ́ wọn;+Àmọ́ a ó pa àtọmọdọ́mọ àwọn ẹni burúkú rẹ́.+
28 Nítorí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo,Kò sì ní kọ àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀ sílẹ̀.+ ע [Áyìn] Ìgbà gbogbo ni yóò máa ṣọ́ wọn;+Àmọ́ a ó pa àtọmọdọ́mọ àwọn ẹni burúkú rẹ́.+