Sáàmù 97:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+ Òwe 2:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ń to ọgbọ́n tó gbéṣẹ́ jọ fún àwọn adúróṣinṣin;Ó jẹ́ apata fún àwọn tó ń rìn nínú ìwà títọ́.+ 8 Ó ń pa ọ̀nà àwọn olódodo mọ́,Ó sì ń ṣọ́ ọ̀nà àwọn adúróṣinṣin rẹ̀.+
10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+
7 Ó ń to ọgbọ́n tó gbéṣẹ́ jọ fún àwọn adúróṣinṣin;Ó jẹ́ apata fún àwọn tó ń rìn nínú ìwà títọ́.+ 8 Ó ń pa ọ̀nà àwọn olódodo mọ́,Ó sì ń ṣọ́ ọ̀nà àwọn adúróṣinṣin rẹ̀.+