Sáàmù 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹni burúkú ń fi ìgbéraga lépa ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́,+Àmọ́ èrò ibi tó gbà máa yí dà lé e lórí.+