Sáàmù 109:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Kí ẹ̀tẹ́ bo àwọn tó ń ta kò mí;Kí wọ́n gbé ìtìjú wọ̀ bí aṣọ.*+