Oníwàásù 9:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Èèyàn kò mọ ìgbà tirẹ̀.+ Bí ẹja ṣe ń kó sínú àwọ̀n ikú, tí àwọn ẹyẹ sì ń kó sínú pańpẹ́, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ èèyàn ṣe ń kó sínú ìdẹkùn ní àkókò àjálù, nígbà tó bá dé bá wọn lójijì.
12 Èèyàn kò mọ ìgbà tirẹ̀.+ Bí ẹja ṣe ń kó sínú àwọ̀n ikú, tí àwọn ẹyẹ sì ń kó sínú pańpẹ́, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ èèyàn ṣe ń kó sínú ìdẹkùn ní àkókò àjálù, nígbà tó bá dé bá wọn lójijì.