Ẹ́kísódù 15:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 O fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ṣamọ̀nà àwọn èèyàn tí o rà pa dà;+ Ìwọ yóò fi agbára rẹ darí wọn lọ sí ibùgbé rẹ mímọ́. Lúùkù 1:68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 “Ẹ yin Jèhófà,* Ọlọ́run Ísírẹ́lì,+ torí ó ti yíjú sí àwọn èèyàn rẹ̀, ó sì ti gbà wọ́n sílẹ̀.+ Ìfihàn 7:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n ń ké jáde pé: “Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wa tó jókòó sórí ìtẹ́+ àti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà ni ìgbàlà wa ti wá.”+
13 O fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ṣamọ̀nà àwọn èèyàn tí o rà pa dà;+ Ìwọ yóò fi agbára rẹ darí wọn lọ sí ibùgbé rẹ mímọ́.
10 Wọ́n ń ké jáde pé: “Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wa tó jókòó sórí ìtẹ́+ àti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà ni ìgbàlà wa ti wá.”+