2 Sámúẹ́lì 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo ké pe Jèhófà nínú wàhálà mi,+Mo sì ń pe Ọlọ́run mi. Nígbà náà, ó gbọ́ ohùn mi láti tẹ́ńpìlì rẹ̀,Igbe mi fún ìrànlọ́wọ́ sì dé etí rẹ̀.+ Sáàmù 10:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ Jèhófà, wàá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Wàá mú ọkàn wọn dúró ṣinṣin,+ wàá sì fiyè sí wọn.+ Sáàmù 34:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ojú Jèhófà wà lára àwọn olódodo,+Etí rẹ̀ sì ṣí sí igbe wọn fún ìrànlọ́wọ́.+ 1 Pétérù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+
7 Mo ké pe Jèhófà nínú wàhálà mi,+Mo sì ń pe Ọlọ́run mi. Nígbà náà, ó gbọ́ ohùn mi láti tẹ́ńpìlì rẹ̀,Igbe mi fún ìrànlọ́wọ́ sì dé etí rẹ̀.+
17 Àmọ́ Jèhófà, wàá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Wàá mú ọkàn wọn dúró ṣinṣin,+ wàá sì fiyè sí wọn.+
12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+