Sáàmù 15:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kì í yáni lówó èlé,+Kì í gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti gbógun ti aláìṣẹ̀.+ Ẹni tó bá ń ṣe àwọn nǹkan yìí, mìmì kan ò ní mì í láé.*+ Sáàmù 125:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 125 Àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà+Dà bí Òkè Síónì, tí kò ṣeé mì,Àmọ́ tí ó wà títí láé.+
5 Kì í yáni lówó èlé,+Kì í gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti gbógun ti aláìṣẹ̀.+ Ẹni tó bá ń ṣe àwọn nǹkan yìí, mìmì kan ò ní mì í láé.*+