Àwọn Onídàájọ́ 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà, nígbà tí o jáde ní Séírì,+Nígbà tí o kúrò ní ilẹ̀ Édómù,Ayé mì tìtì, omi ọ̀run sì ya,Omi ya bolẹ̀ látojú ọ̀run.
4 Jèhófà, nígbà tí o jáde ní Séírì,+Nígbà tí o kúrò ní ilẹ̀ Édómù,Ayé mì tìtì, omi ọ̀run sì ya,Omi ya bolẹ̀ látojú ọ̀run.