Òwe 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí ẹni burúkú bá kú, ìrètí rẹ̀ á ṣègbé;Ohun tó sì ń retí pé òun á fi agbára òun ṣe yóò ṣègbé pẹ̀lú.+
7 Nígbà tí ẹni burúkú bá kú, ìrètí rẹ̀ á ṣègbé;Ohun tó sì ń retí pé òun á fi agbára òun ṣe yóò ṣègbé pẹ̀lú.+