ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 15:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ọ̀tá sọ pé: ‘Màá lépa wọn! Màá lé wọn bá!

      Màá pín ẹrù ogun wọn títí yóò fi tẹ́ mi* lọ́rùn!

      Màá fa idà mi yọ! Ọwọ́ mi yóò ṣẹ́gun wọn!’+

       10 O fẹ́ èémí rẹ jáde, òkun sì bò wọ́n;+

      Wọ́n rì sínú alagbalúgbú omi bí òjé.

  • Lúùkù 12:18-20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Torí náà, ó sọ pé, ‘Ohun tí màá ṣe nìyí:+ Màá ya àwọn ilé ìkẹ́rùsí mi lulẹ̀, màá sì kọ́ àwọn tó tóbi, ibẹ̀ ni màá kó gbogbo ọkà mi àti gbogbo ẹrù mi jọ sí, 19 màá sì sọ fún ara* mi pé: “O ní* ọ̀pọ̀ nǹkan rere tí mo ti tò jọ fún ọ̀pọ̀ ọdún; fọkàn balẹ̀, máa jẹ, máa mu, máa gbádùn ara ẹ.”’ 20 Àmọ́ Ọlọ́run sọ fún un pé, ‘Aláìlóye, òru òní ni wọ́n máa béèrè ẹ̀mí* rẹ lọ́wọ́ rẹ. Ta ló máa wá ni àwọn ohun tí o ti tò jọ?’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́