-
Sáàmù 49:16-19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Má bẹ̀rù nítorí pé ẹnì kan di ọlọ́rọ̀,
Nítorí pé ògo ilé rẹ̀ ń pọ̀ sí i,
17 Nítorí tí ó bá kú, kò lè mú ohunkóhun lọ;+
Ògo rẹ̀ kò ní bá a sọ̀ kalẹ̀ lọ.+
18 Nítorí nígbà ayé rẹ̀, ó ń yin ara* rẹ̀.+
(Aráyé máa ń yin èèyàn nígbà tó bá láásìkí.)+
19 Àmọ́ nígbẹ̀yìn, yóò dara pọ̀ mọ́ ìran àwọn baba ńlá rẹ̀.
Wọn kò ní rí ìmọ́lẹ̀ mọ́ láé.
-