Jóòbù 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 ó wá sọ pé: “Ìhòòhò ni mo jáde látinú ikùn ìyá mi,Ìhòòhò ni màá sì pa dà.+ Jèhófà ti fúnni,+ Jèhófà sì ti gbà á. Ká máa yin orúkọ Jèhófà títí lọ.” Oníwàásù 5:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Bí èèyàn ṣe jáde wá látinú ìyá rẹ̀ ní ìhòòhò, bẹ́ẹ̀ náà ni yóò ṣe lọ.+ Kò lè mú ohunkóhun lọ nínú gbogbo iṣẹ́ àṣekára tó ti ṣe.+ 1 Tímótì 6:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Sọ* fún àwọn ọlọ́rọ̀ inú ètò àwọn nǹkan yìí* pé kí wọ́n má ṣe gbéra ga,* kí wọ́n má sì gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ tí kò dáni lójú,+ àmọ́ lé Ọlọ́run, ẹni tó ń pèsè gbogbo ohun tí à ń gbádùn fún wa lọ́pọ̀ rẹpẹtẹ.+
21 ó wá sọ pé: “Ìhòòhò ni mo jáde látinú ikùn ìyá mi,Ìhòòhò ni màá sì pa dà.+ Jèhófà ti fúnni,+ Jèhófà sì ti gbà á. Ká máa yin orúkọ Jèhófà títí lọ.”
15 Bí èèyàn ṣe jáde wá látinú ìyá rẹ̀ ní ìhòòhò, bẹ́ẹ̀ náà ni yóò ṣe lọ.+ Kò lè mú ohunkóhun lọ nínú gbogbo iṣẹ́ àṣekára tó ti ṣe.+
17 Sọ* fún àwọn ọlọ́rọ̀ inú ètò àwọn nǹkan yìí* pé kí wọ́n má ṣe gbéra ga,* kí wọ́n má sì gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ tí kò dáni lójú,+ àmọ́ lé Ọlọ́run, ẹni tó ń pèsè gbogbo ohun tí à ń gbádùn fún wa lọ́pọ̀ rẹpẹtẹ.+