1 Kíróníkà 16:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀;+Ẹ mú ẹ̀bùn dání wá síwájú rẹ̀.+ Ẹ forí balẹ̀ fún* Jèhófà nínú aṣọ ọ̀ṣọ́ mímọ́.*+ 30 Kí jìnnìjìnnì bá yín níwájú rẹ̀, gbogbo ayé! Ayé* fìdí múlẹ̀ gbọn-in gbọn-in; kò ṣeé ṣí nípò.*+
29 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀;+Ẹ mú ẹ̀bùn dání wá síwájú rẹ̀.+ Ẹ forí balẹ̀ fún* Jèhófà nínú aṣọ ọ̀ṣọ́ mímọ́.*+ 30 Kí jìnnìjìnnì bá yín níwájú rẹ̀, gbogbo ayé! Ayé* fìdí múlẹ̀ gbọn-in gbọn-in; kò ṣeé ṣí nípò.*+