1 Sámúẹ́lì 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tí àwọn ará Áṣídódì dìde ní kùtùkùtù ọjọ́ kejì, Dágónì ti ṣubú, ó sì dojú bolẹ̀ níwájú Àpótí Jèhófà.+ Torí náà, wọ́n gbé Dágónì, wọ́n sì dá a pa dà sí àyè rẹ̀.+ Àìsáyà 46:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n gbé e sí èjìká wọn,+Wọ́n gbé e, wọ́n sì fi sí àyè rẹ̀, ṣe ló kàn dúró síbẹ̀. Kì í kúrò ní àyè rẹ̀.+ Wọ́n ké sí i, àmọ́ kò dáhùn;Kò lè gba ẹnikẹ́ni nínú wàhálà.+
3 Nígbà tí àwọn ará Áṣídódì dìde ní kùtùkùtù ọjọ́ kejì, Dágónì ti ṣubú, ó sì dojú bolẹ̀ níwájú Àpótí Jèhófà.+ Torí náà, wọ́n gbé Dágónì, wọ́n sì dá a pa dà sí àyè rẹ̀.+
7 Wọ́n gbé e sí èjìká wọn,+Wọ́n gbé e, wọ́n sì fi sí àyè rẹ̀, ṣe ló kàn dúró síbẹ̀. Kì í kúrò ní àyè rẹ̀.+ Wọ́n ké sí i, àmọ́ kò dáhùn;Kò lè gba ẹnikẹ́ni nínú wàhálà.+