Sáàmù 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Gbogbo ọ̀nà Jèhófà jẹ́ ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́Fún àwọn tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀+ àti àwọn ìránnilétí+ rẹ̀ mọ́. Sáàmù 91:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Yóò fi àwọn ìyẹ́ tó fi ń fò bò ọ́,*Wàá sì fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ṣe ibi ààbò.+ Òtítọ́ rẹ̀+ yóò jẹ́ apata+ ńlá àti odi* ààbò.
10 Gbogbo ọ̀nà Jèhófà jẹ́ ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́Fún àwọn tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀+ àti àwọn ìránnilétí+ rẹ̀ mọ́.
4 Yóò fi àwọn ìyẹ́ tó fi ń fò bò ọ́,*Wàá sì fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ṣe ibi ààbò.+ Òtítọ́ rẹ̀+ yóò jẹ́ apata+ ńlá àti odi* ààbò.