Sáàmù 100:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí Jèhófà jẹ́ ẹni rere;+Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé,Òtítọ́ rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.+