Sáàmù 89:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Apá rẹ lágbára;+Ọwọ́ rẹ lókun,+Ọwọ́ ọ̀tún rẹ sì ga sókè.+ Àìsáyà 63:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹni tó mú kí apá Rẹ̀ ológo bá ọwọ́ ọ̀tún Mósè lọ,+Ẹni tó pín omi níyà níwájú wọn,+Kó lè ṣe orúkọ tó máa wà títí láé fún ara rẹ̀,+
12 Ẹni tó mú kí apá Rẹ̀ ológo bá ọwọ́ ọ̀tún Mósè lọ,+Ẹni tó pín omi níyà níwájú wọn,+Kó lè ṣe orúkọ tó máa wà títí láé fún ara rẹ̀,+