ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 6:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ní báyìí, wàá rí ohun tí màá ṣe sí Fáráò.+ Ọwọ́ agbára ló máa mú kó fi wọ́n sílẹ̀, ọwọ́ agbára ló sì máa mú kó lé wọn kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.”+

  • Ẹ́kísódù 6:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Torí náà, sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: ‘Èmi ni Jèhófà, màá mú yín kúrò lábẹ́ àjàgà àwọn ará Íjíbítì, màá sì gbà yín sílẹ̀ lóko ẹrú.+ Màá fi apá mi tí mo nà jáde* àti àwọn ìdájọ́ tó rinlẹ̀ gbà yín pa dà.+

  • Ẹ́kísódù 15:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+

      Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta

      Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà,

      Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́