Sáàmù 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí o ò ní fi mí sílẹ̀* nínú Isà Òkú.*+ O ò ní jẹ́ kí ẹni ìdúróṣinṣin rẹ rí kòtò.*+