Sáàmù 119:80 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 80 Kí ọkàn mi jẹ́ aláìlẹ́bi bí mo ṣe ń tẹ̀ lé àwọn ìlànà rẹ,+Kí ojú má bàa tì mí.+