-
Sáàmù 119:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà náà, ojú ò ní tì mí+
Tí mo bá ń ronú nípa gbogbo àṣẹ rẹ.
-
-
1 Jòhánù 2:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Torí náà, ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, ká lè sọ̀rọ̀ ní fàlàlà + nígbà tí a bá fi í hàn kedere, kí a má bàa fi ìtìjú kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀ nígbà tó bá wà níhìn-ín.
-