Sáàmù 51:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Dá ọkàn mímọ́ sí inú mi, Ọlọ́run,+Kí o sì fi ẹ̀mí tuntun sí inú mi,+ èyí tó fìdí múlẹ̀.