Sáàmù 86:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.+ Èmi yóò máa rìn nínú òtítọ́ rẹ.+ Fún mi ní ọkàn tó pa pọ̀* kí n lè máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.+
11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.+ Èmi yóò máa rìn nínú òtítọ́ rẹ.+ Fún mi ní ọkàn tó pa pọ̀* kí n lè máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.+