Sáàmù 51:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Nu àwọn àṣìṣe mi kúrò nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ.+ Sáàmù 90:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀+ tẹ́ wa lọ́rùn ní àárọ̀,Ká lè máa kígbe ayọ̀, kí inú wa sì máa dùn+ ní gbogbo ọjọ́ ayé wa.
51 Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Nu àwọn àṣìṣe mi kúrò nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ.+
14 Fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀+ tẹ́ wa lọ́rùn ní àárọ̀,Ká lè máa kígbe ayọ̀, kí inú wa sì máa dùn+ ní gbogbo ọjọ́ ayé wa.