Sáàmù 119:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Jèhófà,+ kọ́ mi kí n lè máa tè lé àwọn ìlànà rẹ,Màá sì tẹ̀ lé e délẹ̀délẹ̀.+